Alaga igbimọ amusẹya to gba ijọba apapọ Naijiria nimọran lori ọna ti wọn yoo gba sanwo oṣu tuntun fun awọn oṣiṣẹ, Bismark Rewane, sọ pe kii ṣe gbogbo owo ti oṣiṣẹ n gba ni ẹkunwo naa yoo ba. O ṣalaye ...